logo

HOME | HIP HOP | NAIJA | LYRICS« | »

Asa – Happy People Lyrics

Asa – Happy People Lyrics

O òré mi Láídé
Níbo ló dà l’ójó Saturday yìí
Hmmm… Wón se party níhìn o
L’Ókè súnáà léhìn kùlé àwon Làtí

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l’a gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l’a gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Oh we’re happy people
And that’s who we are
We’re having fun
We’re the children of the sun

Oh we’re happy people
And that’s who we are
We don’t care
We’re the children of the sun

O òré mi Laide
Níbo ló kàn l’ójó Sunday yìí
Hmmm… Wón gbéyàwó níhin o
L’Ókè pópó légbe ilé àwon Toyeeb

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l’a gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá
Gèlè búlúù la wò
Kosé l’a gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Oh we’re happy people
And that’s who we are
We’re having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that’s who we are
We don’t care
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that’s who we are
We’re having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that’s who we are
Oh we don’t care
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that’s who we are now
Oh we don’t care
We are the children of the sun

Posted by on October 16, 2019.

Categories: Naija Lyrics

0 Responses

Leave a Reply

« | »
Recent Posts


Pages>